Arábìnrin kan ni aso rè fàya ní enu ìdí látàrí àsejú rè nípa ijó tí ó fé kó mólè dáadáa, kí ó tún owó ijó náà mú láti ilè. Nínú fídíò tí a rí wò, tí a ti yo àwòrán ...
Read More » 
		Awoyemi Bamimore Comments Off on Isé kìí pa ni, ayò ní pa omo ènìyàn
Arábìnrin kan ni aso rè fàya ní enu ìdí látàrí àsejú rè nípa ijó tí ó fé kó mólè dáadáa, kí ó tún owó ijó náà mú láti ilè. Nínú fídíò tí a rí wò, tí a ti yo àwòrán ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Òkan lára Ilé ìgbé àwon akékòó ti Ilé-èkó gíga ifáfitì ti ìlú ilé-ifè tí a mò sí Obafemi Awolowo University gbiná lánàá.
Òkan lára ilé ìgbé àwon Akékòó ti ilé-èkó gíga ifafitì ti Obafemi Awolowo gbiná ní alé àná. Ilé ìgbé yìí a máa jé Alumni hostel, bí ó ti lè je wípé a kò fi tara tara mo bí ó se ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Bàbá Sàlá òrun rere re o. Gbajúgbajà elérí orí ìtàgé, tí gbogbo èèyàn mò sí bàbá Sàlá ti gba òrun lo ní àná ojó kesàn-án osù kèwà odún tí a wà yí.
Tí won bá ni èèyàn apanilérìn ni baba won kò paró rárá, nítorí àwon gangan ni oyè adérìn-ín-p’òsónú ye. Moses Olaiya Adejuwon (M.O.N), lórúko baba súgbón bàbá Sala ti gba orúko lówó won. Àsé kò sí eni tí kò ní ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ìyá omo keta gbajúgbajà olórin tí a mò sí Wizkid, tí orúko ìyà omo náà a máa jé Jada Pollock pín àwòrán omo rè, Zion.
Ìyá omo keta gbajúgbajà olórin tí a mò sí Wizkid, tí orúko ìyà omo náà a máa jé Jada Pollock pín àwòrán omo rè, Zion. Alámójútó Olórin àgbáyé, Wizkid tí ó padà di ìyá omo rè, Jada Pollock pín àwòrán ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Linda Ikeji àti omo rè, tí orúko omo náà n jé Jayce Jeremi nínú àwòrán tuntun.
Gbajúgbajà elétíofe tí gbogbo ayé mò sí Linda Ikeji tí ó sèsè bí omo okúnrin rè ní ojó ketàdínlógún osú kesàn-án odún tí a wà yí, pín àwòrán sí orí èro insítágírámù pèlú omo rè, Jayce. Ó ko síbè wípé… ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ibon !
Awoyemi Bamimore Comments Off on Ògúndá Ọ̀wọ́nrín (Ògúndẹ̀rín)
Àtẹ́lẹwọ́ mi ọ̀tún ni mo fi kọ́’fá ń dídá Mo mọ Ifá ń dídá A dífá fún Akítán tíí ṣe ọmọ’yè Oníkàá Àtẹ́lẹwọ́ mi òsì ni mo fi kọ́bò ní gbígbà Mo mọ ìbò ni gbígbà Dífá fá fún Aṣọ̀gbà ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ejìnrìn Wọ̀jọ ̀wọ̀jọ̀
Ejìnrìn wọ̀jọ ̀wọ̀jọ̀ Awo Ọlọ́wọ̀ ló ṣefá fún Ọlọ́wọ̀ Eléyìí tí yóò roko roko tí yóò gbé kílìṣí tíí ṣe yèyé ajé wálé Ìji lẹ́lẹ́ – Awo Ìji lẹ́lẹ́ Ìji lẹ̀lẹ̀ – Awo Ìji lẹ̀lẹ̀ Ẹ̀fúùfù lẹ̀lẹ̀ ní jági lọ́run ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Stephanie Hornecker wo aso tí oyàn rè n hàn feere níbè, tí ó sì dàbí egbin nínú è
Stephanie Hornecker wo aso tí oyàn rè n hàn feere níbè, tí ó sì dàbí egbin nínú è. Arewà télè tí ó tún jé òsèré orí ìtàgé sùgbón tí ó ti di Olùwòsàn báyìí, Regina Askia pín àwòrán tí ó ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ànto Lecky wo Ejò rògbòdò yíká orún rè
Ará ilé Bbnaija télè tí a mò so Anto ti gbé àrà òtun yo fún àwon olólùfé rè, nígbà tí ó lo sí àgbàlà ejò rògbòdò ní orílè èdè Republic of Benin. Ó ko síbè wípé: ” Ní àgbàlá ejò ...
Read More » Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more