Home / Tag Archives: Àṣà Yorùbá (page 88)

Tag Archives: Àṣà Yorùbá

Nipinle Ondo, eniyan meji koja sorun nibi ija NURTW

O kere tan awon eniyan bi meji ni won gborun lo ni Ikare-Akoko to wa ni ipinle Ondo nigba ti awon eniyan bi mewaa farapa koja bikiafu nibi ija to wayii laaarin awon omo onimoto.   Wahala to bere lati ...

Read More »
Ajimobi fogbon juko oro si Ladoja

Emi ati Alao-Akala ti lepo di okan soso- Gomina Ajimobi

*Ajimobi fogbon juko oro si Ladoja Leyin awuyewuye ati awon oro ti n lo nigboro nipa wi pe gomina tele fun ipinle Oyo, Christopher Alao-Akala n mura lati darapo mo egbe APC ti pada jade lenu Akala funra re bayii. ...

Read More »
lagos

“Ko saaye fun Toll-Gate bayii” – Egbe Akoroyin tiluu Eko

E gbe akoroyin, Nigeria Union of Journalists eka ti ilu Eko, ti gbe atejade kan jade eleyii to n ro ijoba apapo lati se atunse si awon oju ona masose wa ki won to ronu a ti da Toll Gate ...

Read More »

E ba wa dasi oro yii

Nje ohun to dara wa ninu ki awon okunrin maa na awon iyawo ile won? Kini obirin le se to le mu okunrin siwo soke na won?

Read More »
ifa

Àróbá baba ítán: Oral tradition is the key of history

Aboru Aboye ooo “Bó omodé kò bá mo ìtàn Ó ní láti bá àróbá Àróbá baba ítán If a child does not know history He/she must have the knowledge of oral tradition Oral tradition is the key of history….. These ...

Read More »

Awon oun marun-un te e mo nipa awon obirin

Se looto nii

Read More »
ori

Ori kini won gbe sinu obe yii?

E woju obe ke e muyan. Iyan ‘re obe e re!

Read More »
foto

Foto: Kini obirin le se na ?

Kini obirin le se na, to le mu oko re na bi eleyii pelu oyun ninu? Iru iwa awon odaju okunrin bayii bani lokan je gidi. Sebi o se maa ri lo ni yii?

Read More »
ere

Kini oruko awon osere yii?

Inu fiimu wo ni foto yii ti jade?

Read More »
Taye Ogunlaja

Taye Ogunlaja: Won ti pa oloye omo egbe NURTW tiluu Eko

*Won gun un lobe lorun pa ni Awon olopaa olotelemuye, eka ti ile ise olopaa ti n risi iwa idaran to wa ni Panti, Yaba ti bere ise iwadii to gbepon bayii lati mo odaju eda to seku pa Taye ...

Read More »

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb