Home / Art / Àṣà Oòduà (page 35)

Àṣà Oòduà

Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

Olorì Basirat tí ó pé odún mókàndínlógún ni ojó mélòó séyìn ya àwon àwòrán tí ó wuyì.

Olorì oba àti ìyá ìbejì ni a gbó wípé ó máa n dá oba lóhùn láàfin àti wípé òhun ni ó máa n pèsè gbogbo nkan tí Kábìèsí fé láàfin àti ní orí èro ayélujára. A gbó wípé kò sí ...

Read More »

Òsèré Yvonne Jegede àti Oko è kí omo tuntun káàbò tí ó tún jé àkóbí won.

Gbajúgbajà Òsèré Yvonne Jegede Fawole àti oko rè dun nú nígbà tí won bí omo tuntun tí ó tún jé Àkóbí won. Bí ó ti lè jé wípé a kò tí mò bóyà ako ni àbí abo sùgbón a mò ...

Read More »

Ká ṣojú ẹni Ká sẹ́yìn ẹni Orúkọ tí à á pe ìránṣẹ́ (ìbò) .

Òtítọ́ wọn kò sí láyé mọ́ Aṣẹ̀yìn deni wọn kò wọpọ̀ Àbàtà ńlá abojú dẹ̀gun dẹ̀gun Ká ṣojú ẹni Ká ṣẹ̀yìn ẹni Àwọn mẹ́rẹ̀ẹ̀rin ní ọmọ ìkọ́fa Ilé Àgbọnnìrègún Baba kọ́won ní dídá ọwọ́ Wọ́n mọ̀ ọ́n dá Ifá kọ́won ...

Read More »

Akékòó okùnrin tí ó ti wà ní ìpelè tí ó parí ní ilé-èkó gíga polytechnic ti ìlú Oko ni won yìnbo fún tí ó sì kú.

Arákùnrin kan ni won yìn ìbon fún ní ilé-èkó gíga polytechnic ti ìjoba ní Oko ní ìpínlè Anambra. Gégé bí ìròyìn se so, olóògbé tí gbogbo èèyàn mò sí ‘ De moon’ jé Akékòó féè pari tí ó sì jé ...

Read More »

Davido àti Kiss Daniel nínú o okò ojú òfurufú.

Davido àti Kiss Daniel nínú o okò ojú òfurufú. Gbajúgbajà olórin àti ìlú mòóká olórin tí gbogbo ayé mò sí Wizkid àti Kiss Daniel ya àwòrán papò nínú okò ojú òfurufú aládani. Nse ni ó dàbí eni wípé won fé ...

Read More »

Toke Makinwa nínú aso ìwè nígbà tí ó lo sí èbá òkun ní ìlú Èkó.

Gbajúgbajà ò n lò èro ayélujára tí a mò sí Toke Makinwa tí gbé ògo tí olórun fún hàn, nígbà tí ó gbé àwòrán ìgbà tí ó wo aso ìwè sí orí èro ayélujára tí ó n jé Ínsítágírámù . ...

Read More »

Gbajúgbajà olórin tí a mò sí Yemi Alade rèdí fún, ìlúmòókà olórin tí a mò sí Flavour.

Gbajúgbajà olórin tí a mò sí Yemi Alade rèdí fún, ìlúmòókà olórin tí a mò sí Flavour. Gégé bí òrò ata díndín tí ó gbòde kan, òrò nípa Tiwa Savage àti Wizkid tí àwon èèyàn n gbà, tí won sì ...

Read More »

Ogbè Ògúndá (Ogbèyọ́nú)

Ifá pé òun yóò ṣe oore òjijì fún ọmọ Ogbèyọ́nú tàbí ẹni yòówù tí a dáfá yìí fún. Ifá pé ìgbàgbọ́ rẹ̀ kò tó nǹkan nínú òun; pé kó lọ ní ìgbàgbọ́ tó jinlẹ̀ síwájú síi nínú òun Ọ̀rúnmìlà. Ifá ...

Read More »

Oònirìsà sòrò nípa bí àwon èèyàn se n so kiri wípé èjè ni olorì tuntun tè mólè.

Oònirìsà sòrò nípa bí àwon èèyàn se n so kiri wípé èjè ni olorì tuntun tè mólè. Oònirìsà ti jé kí á mò wípé yèyélúwà kò te èjè mólè rárá àti wípé Osùn ni Oluwaseyi Moronke, Yèyélúwà tuntun tè mólè ...

Read More »

Kò kò, ó gbà láti se ètùtù, Moronke Naomi Oluwaseyi gbà láti se òun tótó gégé bí olorì àkókó láàrin àwon olorì pátápátá.

Bí won se ni kó se é ló se é. Bí ó tilè jé wípé àtúnbí nínú Jésú ni, kò kò láti se àwon ohun tí ó tó gégé bí olorì láàfin Oòni ti ilé-ifè. Àwòrán ibi tí ìyàwó ti ...

Read More »

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb