Home / Tag Archives: Àṣà Yorùbá (page 67)

Tag Archives: Àṣà Yorùbá

idunnu

Ounje emi fun t’ooro yii ( 20 – 07 – 2016 )

HUN !!! # Odo to gbagbe # Orisun … Gbigbe nii gbe … WOO ORE WA !!! Ibi  Ipile eda L’orisun won.. Ibi  Eniyan ti lalehu ni Ipile re… Eni to bini ‪Orisun‬ eni nii se… ‪Eniyan‬ to wo’ni dagba ...

Read More »

Iyawo: mi o le gba ki iya oko mi gbe pelu mi lailai.

Olotu:kini ikan tori tofi ni o le gba ki iya gbe pelu re,gbogbo awon eyan loti ba e so,o ko,o loni gbo,won tun gbe e wa sori afefe,agidi yi nan lotun lo.Kini ikan to sele gan. Iyawo:seri olotu,mole gba ki ...

Read More »
olojo ibi

Olojo Ibi Toni

Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi Alfa Ola Akeem Totofun’un ti won je okan pataki ninu ebi Ooduarere. Olojo ibi oni a ki yin e ku ayo oni, e o se pupo re laye ninu ...

Read More »
Odu ifa otura meji

Ojumo Ire

B’ojumo ba mo .. Ooye a la ‪#‎peregede‬.. A D’ifa fun Peregede tii se yeye ‪#‎Ojumo‬ . A KU OJUMO #Ojumo to mowa Lonii. ‪#‎Ojumo_Ire‬ gbogbo ni yoo je funwa lase Oba mi Oke .

Read More »
odu ifa

Iwure owuro ojo oni 17/07/2016

E maa wi tele mi : *Edumare pese owo irorun fun mi. *Edumare dakun faanu wa mi ri. *Edumare ma fi mi daamu aye. *Eleda a mi ma faye daamu-un mi. *Ogun roju je roju mu koni je temi *Egun ...

Read More »
elesin

Elesin Oyan

Iba Orunmila Bara Agbonniregun; Elesin Oyan; Adagbaa Ojomu; Gbolajoko Omo Ere l’apa; Baba Okinkin ti n m’eyin erin fo; Odudu tii du ori emere ti o je ko fo; Atori eni ti ko sunwon se! Iba Baba o!

Read More »
ooduarere

Feeling lonely does not mean that you are alone

It just means that you have others around you that do not share the same emotions. Loneliness can be felt even if you have people around you. It is the emotional loneliness that makes you sad. But now you have ...

Read More »
obaluaye

Oniwowo ado! Baba dakun ma na mi o! Aase!

OBALUAYE!!!!!! OOOOOOO cc- Babalawo Ifakayode Oyedele Osaifa

Read More »
saheed

Foto ode’oni – 13.07.2016

Saheed osupa akorede ati baba wande.

Read More »
olorin

Ejowo eni to ba mo olorin yi ko ko oruko re

Edakun kini oruko olorin yii

Read More »

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb