Eng Seyi Makinde, okan ninu awon oludije ipo gomina nipinle Oyo, labe egbe oselu SDP ninu eto idibo odun 2015 to waye ni yii pelu aya re. Gege bi iwadii Olayemi Oniroyin lati enu awon to sun mo eni ti ...
Read More »
admin Comments Off on E wa wo ohun ti oludije ipo gomina n se lagbala pelu aya re.
Eng Seyi Makinde, okan ninu awon oludije ipo gomina nipinle Oyo, labe egbe oselu SDP ninu eto idibo odun 2015 to waye ni yii pelu aya re. Gege bi iwadii Olayemi Oniroyin lati enu awon to sun mo eni ti ...
Read More »admin Comments Off on Kini ijoba n se nipa awon ti n se ayederu?
Orisun iwe Iroyin Iroyin yii kii se tuntun, yoo si ti to bi osu kan o le die ti asiri awon to n se ayederu elerindodo Coca Cola ti jade. Sugbon iru awon iroyin bayii, a kan maa n gbo ...
Read More »admin Comments Off on Fila o dun bi ka moo de…
Oni fila yii
Read More »admin Comments Off on Idi pataki meta ti ko fi ye ka maa fi ehin je eekanna
1. Ehin le yingin tabi ki die kan lara ehin wa: Nigba mi-in ti a ba n gbiyanju lati fi ehin ge eekanna wa, ehin wa le lura won lojiji, eleyii si le fa ki ehin yingin legbe kan tabi ...
Read More »admin Comments Off on Tinuola Oyindamola pegede!
Oni ni ojo-ibi Omidan Tinuola Oyindamola, okan ninu awon ti won karoyin wa lojoojumo. Adura wa ni wi pe ke e dagba ninu ogbon, ola ati alaafia.
Read More »admin Comments Off on Ofin mokanla to le mu awo ara dabi omo tuntun jojolo
Orisun 1 E yee sa ara yin sinu oorun koja bo ti ye lo. Paapa julo, e sora fun awon oorun lati bi ago mewaa aaro si ago meji osan. Orisii oorun yii a maa mu ki awo eniyan o ...
Read More »admin Comments Off on Dele Momodu se afihan Madueke nigba keji
Fun awon ti ko mo, Dele Momodu ni oniroyin akoko to koko se afihan foto Diezani Alison-Madueke. Eleyii to ya nigba to se abewo si minisita fun epo robi nigba kan ri ni ilu London.Oga Dele Momodu ti pada se ...
Read More »admin Comments Off on “Iyawo mi n yale, o tun bimo ale fun mi”: Alabi yari ni kootu Ikorodu
Orisun Ogbeni Alabi Rasheed, eni odun mejidinlaadota (48) ti gbe iyawo re, Sherifat, lo si ile ejo lati tu yigi igbeyawo odun mewaa to wa laaarin won ka lOjobo ose to koja yii. Gege bi alaye Alabi ni Ikorodu ...
Read More »admin Comments Off on Saraki gba Basketmouth lalejo niluu Abuja
Aare ile igbimo asofin agba, Bukola Saraki, gba Basketmouth lalejo ninu ile re to wa niluu Abuja
Read More »admin Comments Off on Awon akekoo LASU yari, won ni awon alase n ko leta si yanponyanrin
Lati Ọwọ Olayemi Olatilewa Awon omo egbe akekoo Ifafiti tilu Eko, Lagos State University Students Union (LASUSU) ti bere si ni fariga pelu ifehonuhan latari bi awon alase ileewe naa se fi owo kun owo igbaniwole awon akekoo tuntun. Ifehonuhan ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more