Òdómokùnrin méta kan ni owó àwon civilian Joint Task Force Nígbà tí won jalè lówó ní Jato Aka ní ìpínlè Benue tí won pa wón ní bíi agogo méjì òwúrò òní (2am). Gégé bí ìròyìn se so, àwon olè náà, ...
Read More »Ta Ni Elújoba?
Elújoba ni gíwa tí ó kúrò Lóríi oyè gégé bíi alásé oau Láìpé yìí Tí gbogbo ènìyàn sì n kan sárá sí òjògbòn náà kìí kúkú se pé wón n déédé kan sáárá sí Baba Ìwà rere àti òótó inú ...
Read More »Àsírí sèsè tú sí won lówó wípé ilé-isé mi ní iye owó tí ó tó Dólà lónà ogóòrun Mílíònù ($100 million) -D’banj.
Kokomaster tí a tún mò sí D’banj le sèsè di òsèré tí ó lówó jù ní ilè adúláwò (Africa). Olórin tí ó sì jé baba omo kan sèsè gbe sí orí èro ayélujàra (instagram) rè pé Cream platform tí ó ...
Read More »Gáàsì bú gbàmù ní Cross river tí ó sì pa èèyàn méji, tí ó fa ìpalára fún àwon mérin nínú ebí.
Àwon omo ebí mérin ti igbákejì adarí kíko eré ìdárayá ní orílè èdè Nàìjíríà ” Vice President of Sport Association (SWAN), Eddie Bekom tí a gbà sí ilé-ìwòsàn léyìn ìgbà tí gáàsì tí wón fi ń dáná bú gbàmù láti ...
Read More »Yakubu Gowon lo kí Shehu Shagari.
Olórí ìpínlè télè (former head of state) General Yakubu Gowon lo kí Ààre ti télè Shehu Shagari ní ilé rè ní Sokoto. Gómìnà Tambuwal sìn-ín lo pèlú Olórí àlùfáà Ìjo Catholic ti Sokoto, Bishop Matthew Hassan kukan àti àwon ènìyàn ...
Read More »Annie Idibia da padà fún olùtèlé rè tí ó pè é ní omobìnrin tó “wor wor “.
Annie Idibia fi àwòrán yí sí orí èro ayélujàra rè (instagram) tí ó rò wípé kò rewà pè é ní omobìnrin tó ” wor wor ” . Ìyá omo méji tí òhun náà sì da padà fun pé :bí ìyá ...
Read More »Falz àti 9ice je oúnje alé papò (àwòrán, fídíò).
Falz ti fi èsì àìgbó ra eni ye hàn láàrin òun àti 9ice nígbà tí òpò rò wípé 9ice ni ó ń báwí nígbà tí ó ń gba àwon olórin ní ìmòràn kí won má fi Orin yin àwon gbájúè ...
Read More »Olúbàdàn kìlò kí won má se jàgídíjàgan bí odún egúngún se fé bèrè.
Gégé bí odún egúngún odoodún se ma bèrè l’óla, ojó ajé, ní ìlú Ibadan, ní ìpínlè Oyo, Olúbàdàn ti ilè Ibadan, oba Saliu Akanmu Adetunji ti pè fún àláfíà láti òdò àwon eléégún àti àwon tí ó ń tèle tí ...
Read More »Àwòrán láti ìlú olómìnira kan tí a mò sí Ewédú àti ìgbálè
Àwòrán láti owó omo oòduà rere. Àwòrán láti ìlú olómìnira kan tí a mò sí Ewédú àti ìgbálè (a fé béè, èrín yakata). Ta ló tún n’ìfé àwòrán láti ìjìnlè ìlú yorùba? N’ísàlè ni àwòrán àjò lo sí ìlú Iseyin ...
Read More »Àwòrán : afurasí omo egbé òkùnkùn kan tí a mò sí Baddo ni owó tè ní Ikorodu.
Afurasí omo ògbó-n-tarìgì egbé òkùnkùn, Baddo, ni owó tè ní Ikorodu ní ìpínlè Èkó Lánàá tí osù kefà di ogbòn (June 30th) gégé bí àwon olùgbé àdúgbò se so, a rí Arákùnrin yí tí ó ń rìn káàkiri agbègbè Obafemi ...
Read More »