#Ogulutu Nigba ti mo wa ni kekere, awon egbon adugbo kan wa, awon ti awon obi wa gba wi pe won nimo ju wa lo. Ti o ba ti n to akoko fun awon egbon ti wa lati wo ile ...
Read More »Ayeye Ojo Ibi Oba Lamidi
Oba Alhamis Olayiwola Atanda Adeyemi, Alaafin ti ilu Oyo, pe eni odun metadinlogorin (77) lojo keedogun osu kewaa odun yii loke eepe. Ayeye ojo ibi Oba Lamidi ni Omooba Akeem Adeyemi, eni to je okan lara awon omo ile gbimo ...
Read More »Awon olokada rogo lowo olopaa ilu Ibadan: Won ni ese nla ni lati gbero meji seyin.
Orisun Awon olokada rogo lowo olopaa ilu Ibadan: Won ni ese nla ni lati gbero meji seyin. Olayemi Olatilewa Awon olopaa ilu Ibadan ti bere si ni mu awon olokada ti won ba ti ko ju ero kan lo seyin ...
Read More »Aye akamara: Abiyamo gbe omo re ta nitori owo
Owo awon osise alaabo ti won dabo bo dukia ijoba, Nigerian Security and Civil Defense Corps, NSCDC, e ka ti ipinle Enugun ti te arabirin kan to fe ta omo bibi inu re ni egberun lona ogorun owo naira Naijiria. ...
Read More »Awon olopaa ti lo ko awon omo egbe okunkun n’Ijebu-Ode
Orisun Awon olopaa ti lo ko awon omo egbe okunkun n’Ijebu-Ode *Komisanna lo pase fun awon olopaa Olayemi Olatilewa Owo awon olopaa ipinle Ogun ti te awon afura si kan gege bi omo egbe okunkun ni Ijebu-Ode. Gege bi atejade ...
Read More »Fayose kede nomba ero ibanisoro re fun awon eniyan ipinle Ekiti
Gomina Ayo fayose ti kede nomba ero ibanisoro re lori eto olosoosu kan to maa waye lori redio ati telifisan ipinle Ekiti, “E PADE GOMINA”. Lori eto yii ni gomina ti n jiyin awon ise iriju re fun awon eniyan ...
Read More »Se eru nla FIFA ko ni wo Issa Hayatou lorun?
Bi o tile je wi pe iriri odun metadinlogbon (27) ni Ogbeni Issa Hayatou ti ni nipa didari ajo to n ri si ere boolu ile Afirika, Confederation of Africa Football. Sibesibe awon ololufe ere boolu ni awon ilu okeere ...
Read More »Niluu Abeokuta, apata wo pa iya ati awon omo re
Niluu Abeokuta, apata wo pa iya ati awon omo re. Olayemi Olatilewa Apata kan ti n be loke tente ni agbegbe Iberekodo niluu Abeokuta ti ye lule to si seku pa iya ati awon omo re. Bi eniyan ba je ...
Read More »ILERA LORO: Bi a se le se itoju ehin enu wa
#Oniroyin @OlayemiOniroyin Aridaju iwadii ti fi ye wa wi pe osan orombo dara pupo ni mimu eleyii to n fun erigi ehin wa ni agbara. Mimu osan orombo ran erigi lowo lati le mu ehin enu wa duro daada nipase ...
Read More »Obirin to bi ibeta ni yii leyin ti Boko Haram gba ile lowo won
Arabirin yii bi ibeta (omo meta) ni ipago ti won pese fun awon eniyan ti Boko Haram so di alainile lori to wa ni Bama ni ipinle Borno. @OlayemiOniroyin
Read More »