Ogbà Obafemi Awolowo University (OAU) ti kó sí inú dàrúdàpò nígbà tí òpò akékòó tò lo sí àgó olóòpá tí ó wà ní Moore ní ìlú ile-ife láti bèèrè fún ìdásílè àwon akegbé won tí àwon ìgbìmò ìdábòbò Ogbà náà ...
Read More »
Awoyemi Bamimore Comments Off on Àwon apàse ilé-ìwé Obafemi Awolowo University (OAU) pàse kí won mú àwon akékòó látàrí àtakò àláfíà (peaceful protest) tí won ń se.
Ogbà Obafemi Awolowo University (OAU) ti kó sí inú dàrúdàpò nígbà tí òpò akékòó tò lo sí àgó olóòpá tí ó wà ní Moore ní ìlú ile-ife láti bèèrè fún ìdásílè àwon akegbé won tí àwon ìgbìmò ìdábòbò Ogbà náà ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Àrùn tí ó gbòde kan tí ó ń jé MONKEY POX.
E jòwó e jé kí á kíyè sí ara wa pèlú owó bíbò (hand shake), sísún mó ara eni tàbí ònà míràn. Àrùn kan ti gbòde ní ìpínlè Bayelsa tí won pè ní *MONKEY POX*.Àrùn tí ó máa ń ràn ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Àwòrán ìsìnkú Odudu Davis, olóòpá tí ìbon àwon olóòpá ojú omi bà tí ó sì kú ní ìpínlè calabar.
Ní’sàlé ni àwòrán ìsìnkú olóyè nínú ológun (Corporal) Odudu Davis tí ìbon pa nígbà tí osù kàrún di ogbòn ní inú odún yìí (30/5/2017)láti owó àwon olóòpá ojú omi (naval officer) nígbà tí àwon olóòpá àti àwon olóòpá ojú ...
Read More »A kú àyájó odún *Òmìnira* ti *orílè Èdè Nàìjíríà* ?? lónìí ooo. Èmí wa yóò se púpò rè láyé. E jòwó, e má sì gbàgbé láti se *ìwúre* fún orílè èdè *Nàìjíríà* ?? nítorí wí pé *”Ìròrùn igi ni ìròrùn ...
Read More »ayangalu Comments Off on Arewa Toni
ayangalu Comments Off on Oga Bello àti iyalode Binta Mogaji
Awon agba osere apanilerin meji
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ìyàwó mi dára sùgbón kò n’ìfé ìbálòpò léyìn ìgbeyàwó.
Ìyàwó mi dáa tí mo sì le pè ní aya rere sùgbón kìí gbà kí á bá ara wa lò nígbà tí ó ye, lóòtó aní omo okùnrin pèlú obìnrin. E jò ó kí ni mo le se? Mo ti ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Kílódé tí àwon omoge fi n’ìfé àwon tí ó ti n’íyàwó.
E jòwó mo fé kí e dá mi lóhùn dáadáa. Gbogbo àwon Òré mi tí ó ti n’íyàwó n’ílé ni òpò obìnrin ń súré tè lé, tí ó sì jé wípé àwon àpón bí ti àwa yí obìnrin díè ni ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ìjàmbá ńlá okò kan tí ó ń jé Nissan Rogue selè ní òpópónà afárá 3rd mainland (3rd mainland bridge).
Okò tí ó ń jé Nissan Rogue àti Toyota Dyna kolu ara won ní òpópónà afárá 3rd mainland (3rd mainland bridge) ósì dà bí eni wípé okò Nissan Rogue náà wón ju iye tí won na lò. Àwon LRU ti ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Mi ò ní dá DMs lóhùn mó – Davido so béè léyìn ìgbà tí ìkan nínú àwon olólùfé rè pa iró mo wípé òun ni ó kókó síde ìbáraenisòrò.
Ògá àkójopò HKN, Davido, tí ó pe ìkan lára àwon olólùfé rè obìnrin jáde, Sheilah Parker, tí ó gbe lo sí orí èro ayélujàra (snapchat ) láti p’aró mo wípé òun ni ó kókó síde ìbáraenisòrò pèlú arabìnrin náà. Olórin ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more