Sebi ojo gbogbo ni tole, ojo kan pere ni tolohun. Owo awon olopaa ilu Eko ti te omo gambari onijibiti kan ti oruko re n je Mohammed Isah, to lu komisanna ipinle Ondo ati Anambra ni jibiti. Omokunrin onijibiti naa ...
Read More »“Kosi ona ti a fe gbegba, ijoba ni lati yo owo iranwo ori epo kuro” – Oyegun
Alaga egbe oselu APC, oloye John Odigie-Oyegun ti fi da awon omo Naijiria loju wi pe, kosi ipadaseyin ninu yiyo owo iranwo ori epo robi. Oyegun lo n soro yii nigba ti n gbalejo awon iko kan lati inu egbe ...
Read More »“Ajo NFF kii ta agbaboolu soke okun” Aare NFF
Ogbeni Amaju Pinnick to je aare ajo ti n risi ere boolu alafesegba, Nigeria Football Federation, ti fesi lati tako awon aheso kan ti n lo nigboro wi pe, ajo NFF n se bisineesi tita agbaboolu soke okun. O ni ...
Read More »Esun idigunjale la o fi kan eni to ba gbegidina ti n gbowo odun” Olopaa Ipinle Ogun
Komisanna awon olopaa ipinle Ogun, Ogbeni Abdulmajid Ali ti kede wi pe,ile ise olopaa ipinle Ogun ti wa ni imurasile lati gbogun ti iwa idaran to seese ko suyo lasiko poposinsin odun taa wa yii. Ninu oro Ogbeni Abdulmajid, eleyii ...
Read More »A se iru eniyan bayii ni Gani Adams, e gbo ohun ti won so nipa re
E ni lati fi eti ara yin gbo ohun ti Omooba Yomi Tejuosho so nipa Oloye Gani Adams. Eniyan ti a n ri lokeere, aimoye nnkan ni e ko mo nipa eni naa.rara.
Read More »Se oro Buhari ko ta leti awon asofin ni?
Okan ninu awon asofin, Honourable Essien Ekpenyong Ayi (PDP) lati ipinle Cross River n sun ni akoko ti Aare Buhari n ka iwe eto isuna odun 2016 niwaju ile igbimo asofin Abuja.
Read More »E wo ohun ti oyinbo amunisin se lodun 1908
Awon oyinbo amunisin lati ilu Belgium yegi fun omokunrin, omo odun meje (7) niluu Congo lodun 1908. Ogbeni Femi Fani-Kayode lo se afihan foto yii lori ayelujara. Okunrin naa si tun fi kun un wi pe, ninu awon oyinbo amunisin to ...
Read More »Yunifasiti ijo Mountain of Fire yoo bere eko kiko lojo Monde
Gbogbo eto ti to bayii fun ileewe giga ti ijo Mountain of Fire and Miracles Ministries (MFM) eleyii ti won pe ni Mountain Top University lati bere eko kiko fun awon akekoo lojo Monde ose yii, 21/12/15. Eto ibere eko ...
Read More »E Sora! FRSC ti kede oju ona to lewu n’Ijebu
Orisun iwe Iroyin: Lati Ọwọ Olayemi Olatilewa Awon eso oju ona ile Nigeria, Federal Road Safety Commission (FRSC), eka ti Ijebu Ode ti kede awon oju ona to lewu ni gbigba fun awon onimoto ni akoko poposinsin odun yii. Oju ...
Read More »Oselu Kogi: “Idi ti a ko fi yan Faleke ni yii” – Alaga APC
Alaga fun egbe oselu APC lapapo, Oloye John Odigie-Oyegun ti salaye idi pataki ti awon agba egbe naa fi pamopo lati yan Alhaji Yahaya Bello gege bi oludije ti yoo ropo Abubakar Audu, eni to jade laye saaju ki eto ...
Read More »