Oríkì ní ilẹ̀ Oòduà.
Read More »
ayangalu Comments Off on Oríkì ní ilẹ̀ Oòduà.
Oríkì ní ilẹ̀ Oòduà.
Read More »Yes, I am angry the way things are in the current state of Nigeria and that feeling is not directed against any race in Nigeria but all the leaders that have failed the people. I had to take a chill ...
Read More »Lolade Comments Off on Oldest King in Oodua Land passes on at 141
Oba Afolabi was believed to be the oldest King in Oyo state as he was said to be 141 years old. The late monarch was born to the Afolabi family in Ilua, in 1879 and was enthroned as king in the ...
Read More »admin Comments Off on I love Oodua wins
A poll between I love Yoruba or I love Oodua took place and latter won by a large margin. Ooduarere.com favourite cap on Twitter profile pic and facebook will be replaced with I love Oodua.Other social media profile picture will ...
Read More »ayangalu Comments Off on Iṣẹ́ ìránṣẹ́ kò sí fún ìmẹ́lẹ́ èèyàn – Tunde Bakare
Fẹ́mi Akínṣọlá Ayé ló bàjẹ́ tí ọmọ olè ń dájọ; oníkálukú mọ ẹ̀tọ́ tó yẹ́’.Olùṣọ́ àgùtàn Tunde Bakare ṣàlàyé bí ìdámẹ́wàá ṣe bẹ̀rẹ̀ ninu Bíbélì àti pé kò si ẹni tí wọ́n gbé ìbọn tì pé dandan ni kó san ...
Read More »ayangalu Comments Off on Àfikún owó oṣù nìkan lẹ̀rọ̀ ìyanṣẹ́lódì- NLC
Àfikún owó oṣù nìkan lẹ̀rọ̀ ìyanṣẹ́lódì…NLC Fẹ́mi Akínṣọlá Ẹgbẹ́ òṣìṣẹ́ lorilẹede Nàìjíríà, NLC, ti sọ fún àwọn adari ẹgbẹ́ ọhun láwọn ipinlẹ pé kí wọ́n gbaradi fún ìyanṣẹ́lódì, bẹrẹ láti ọjọru, ọjọ Kẹrindinlogun oṣù Kẹwàá ọdún 2019.Ẹgbẹ́ NLC ní òun ...
Read More »ayangalu Comments Off on Àyájọ́ ‘Má wọ kọ́mú’
Àyájọ́ ‘Má wọ kọ́mú’ ló kò yìí, kín làkíyèsí ẹ̀yin obìnrin lórí àìsàn jẹjẹrẹ ọyàn Fẹ́mi Akínṣọlá Ọjọ́ Kẹtàlá oṣù Kẹwàá ọdọọdún ni àyájọ́ ọjọ́ ‘Má wọ kọ́mú’ lorilẹede Nàìjíríà eyi tó ń sọ fún àwọn obìnrin láti bá kọ́mú ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ìjọba ṣe tán láti bẹ̀rẹ̀ sí ní gbowó orí lóri ìbáraẹnisọ̀rọ̀
Ìjọba ṣe tán láti bẹ̀rẹ̀ sí ní gbowó orí lóri ìbáraẹnisọ̀rọ̀ Fẹ́mi Akínṣọlá Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àbùùbùtán oore lọ̀rọ̀ sísọ jẹ́ ,fáwa ọmọ aádámọ̀,ọ̀làjú àsìkó yìí,ti fẹ́ mú kí nǹkan ó gbọ̀nà ọ̀tun yọ,bí ó ti jẹ́ pé ...
Read More »ayangalu Comments Off on Yẹ Kí Nàìjíríà Dín Iye Àwọn Sẹ́nétọ̀ Tó Ń Ṣojú Wọn Kù Tàbi, Ka Kúkú Pa Ipò Náà Rẹ́ – Fayemi
Ó yẹ kí Nàìjíríà dín iye àwọn Sẹ́nétọ̀ tó ń ṣojú wọn kù tàbi, ka kúkú pa ipò náà rẹ́ …..Gomina ìpínlẹ̀ Ekiti Fẹ́mi Akínṣọlá Ó ní àwọn sẹ́nétọ̀ tí ń náwó tó pọ̀jù léyìí tí Ìjọba yí le fi ...
Read More »ayangalu Comments Off on Oriki Ori
Ori Onise Apere Atete gbeni ju Orisa Ori atete niran Ori lokun Ori nide Ko si Orisa ti dani gbe leyin Ori eni Ori ni seni ta a fi dade owo Ori ni seni ta a fi tepa ileke woja ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more