Recent Posts

Best Reviews

Naija Gist

Local News

Entertainment Gist Nigeria

  • ookun
  • annie dibia
  • Review Adajo Sope Part 1 2 Blaspheme
  • Ife Ni
  • dammykrane tapjets
  • toyin
  • arole
  • naija gist jokes
  • crying woman

The Buzz Central

News From Nigeria

iraq

Battle For Mosul – June 27, 2017: ISIS Launches Surprise Counter-Attack

Voiceover by Harold Hoover Last weekend ISIS launched a large-scale surprise attack against government forces in the Iraqi city of Mosul. Terrorists attacked the neighborhoods of al-Tanak, Nahrwan, and al-Yarmuk, engaging Iraqi security forces (ISF) in a series of intense firefights. While ISF was fighting terrorists in the Old Mosul area, ISIS used underground tunnels and sleeper cells to push the attack deep inside the government-held part of western Mosul. By Tuesday, ISIS had allegedly captured the embattled neighborhoods despite ...

Read More »
idanwo

Èsì ìdánwò wo ló dára jù tí o ti gbà gégé bi akékòó ifáfitì tí kò tì parí ? 

Gégé bí akékòó tí kò ti parí ní ilé-ìwé gíga ifáfitì, àsìkò kan wà tí a ó rò wípé ayé ti ń se wá, àsìkò kan sì wà tí a ó rò wípé a ga ju ayé lo. Ohun tí ó le fa àsìkò yí ni tí èsì ìdánwò bá jáde. A ti gbó nípa akékòó t’óbú gbàmù s’ékun tàbí se ohun tí ó burúkú jù béè lo, elòmíràn leè para rè látàrí èsì ìdánwò. Sùgbón ní ibí a ó ...

Read More »
transifoma

Gómìnà Yahaya Bello ri èro amúnáwà (Transformer) gégé bí isé rè àkókò ní ìpínlè Kogi. 

Gégé bí ìròyìn se so, Gómìnà ìpínlè Kogi: Yahaya Bello ri èro amúnáwà tí agbára rè tó Egbèédógún (300KVA) ní òpópónà kan ní Lokoja gégé bí isé rè àkókó léyìn tí ó ti lo odún kan àti ààbò lórí ipò. Ìkan lára ò n lò èro ayélujàra (facebook) tí ó pin àwòrán náà, ó Ko síbè pé : ó lo pèlú okò tí ó tó ogún tí gbogbo rè férè jé SUV láti lo sí isé takuntakun tí ó se ...

Read More »
pasito

Owó te olùsó àgùntàn(pastor) èké kan nígbà tí ó ń gbìyànjú láti ri ohun tí a kò mò sí ilé onílé. 

Olùsó àgùntàn èké kan tí a mò sí Osinachi Christopher láti ìpínlè Abia ni won fi s’èsín léyìn ìgbà tí owó ti tèé nígbà tí ó ń gbìyànjú à ti ri ohun tí a kò mò sí ilé onílé ní agbègbè Nnobi ní ìpínlè Anambra . Gégé bí eni tí ó pin se so èyí kó ni àkókó tí Olùsó àgùntàn náà ma se èyí. Ka ohun tí Uzochukwu Onuabuchi so ní ojó etì tí ó kojá, ojó ketàlélógún osù ...

Read More »

Latest World News