Recent Posts

Best Reviews

Naija Gist

Local News

Entertainment Gist Nigeria

  • Iyanya
  • anthony joshua
  • rich
  • temi
  • davido naira marley
  • Ifeanyi Ezeokeke
  • asa
  • Kolawole Ajeyemi

The Buzz Central

News From Nigeria

court

Àwọn agbẹjọ́rò ta ko ìnáwó àti òfin kó-nílé-ó-gbélé Ààrẹ àti àwọn gómìnà

Orisiirisii awon agbejoro ati awon amofin pelu ojogbon lorisiirisii ni won ti n yo suti ete si igbese awon ijoba orileede yii, paapaa julo lori arun coronavirus to gbode. Won ni ko tile tona rara ki ijoba apapo dede kede ki-onile-o-gbele lai fi to awon ile igbimo asofin kekere ati nla leti. Won ni eleyii lodi patapata si ofin ile wa ti odun 1999.Won ni bi a si ti n towo bo owo ilu naa maa leyin nigba ti arun ...

Read More »
Seyi Makinde

Seyi Makinde di gómìnà kẹ́ta tó kó àrùn Covid-19

Oni ogbon ojo, osu keta ni ayewo gomina ipinle Oyo, Alagba Seyi Makinde jade, ti ayewo naa si gbee pe o ni arun naa. Oun ni o maa je eleeketa gomina ni orileede yii ti ayewo fihan pe won ni arun kokoro naa. Gomina ipinle Bauchi, Bala Mohammmed ni o koko ni, ki ayewo to gbe ti gomina ipinle Kaduna , Nazir El-Rufai jade. Eyi lo mu ki gbogbo eka ijoba maa pariwo ki onile ko gbele nitori ajakale arun ...

Read More »
buhari

FG Assisted Fund: Every BVN Holder Should Be Expecting Their ₦30,000 Before the Next 24hours

In the recent statement released by the ministry of finance,the content of the statement affirmed and assured Nigerians who have been expecting the proposed #30,000 by the federal government as a result of the on going lockdown in some parts of the country.It gave assurance that every Nigerians who have Bvn number would be the beneficiary of the wish on pranks and jokes day Although at the mid hours of yesterday,the Minister of Finance, Budget and National Planning,Zainab Ahmed said ...

Read More »
fg

Orí kó ènìyàn márùn-ún yọ lọ́wọ́ coronavirus l’Ekoo

Orí kó ènìyàn márùn-ún yọ lọ́wọ́ coronavirus l’EkooÌròyìn láti ọwọ́ Yínká Àlàbí Alaisan marun-un ninu awon ti arun buruku covid-19 ti n ba finra lati bii ose meloo kan seyin gba idande. Yoruba bo “won ni alaare ko ki n ra si inu yara, bi o segun aisan, yoo fi ese ara re rin jade, bi o ba si yiwo naa, won a gbe oku re jade”.Eyi lo sele si awon marun-un ti arun coronavirus ti n ba poo, ti ...

Read More »

Latest World News