Recent Posts

Best Reviews

Naija Gist

Local News

Entertainment Gist Nigeria

  • wale
  • mayowaekpo
  • 2face
  • toolz
  • adekunle gold
  • omo aje
  • tiwa
  • tiwa
  • flavour

The Buzz Central

News From Nigeria

ijo-ifa

A ku ose Obatala ?

  Tolotolo ti kekere mode Hu rungbon sewure Lo difa fun Obatala Osereigbo Ti won ni o wa joye nile Ifon Obatala ko, o ni oun o joye Ki won fi oun je Baba Arugbo Obatala di Baba arugbo Osereigbo Obatala di arugbo ile Ifon Won bi Obatala lere pe Bo ba d’arugbo tan Iru ise wo ni o maa se Ti ebi ko ni fi paa ku Obatala ni haa! Gbogbo isekise Ti gbogbo awon Irunmole ba n se ...

Read More »
Ara Kenge

Foto: Ara Kenge !

E bami kira fun Ife….gbosa, gbosa, gbosa  

Read More »
asa yoruba

Orin, Owe ati Ewi !

ORIN : ” Ododo-Eye mi, ko ma re danu .. Ko maa re danu, Loju aye mi.. Ile nimo ko o, Oko nimo ra.. Omo,Omo l’adele o… …… OWE : * Agba waa bura bewe o ba se-o ri. * Omo Ta o ko, Ni yoo gbe’le taa ko ta.. * Oromodire nii D’akuko …. EWI : Omo Lere aye Omo N’iyun Omo N’ide.. Omo L’ade-Ori Omo N’ileke orun. Panboto-Riboto.. K’ori je n R’omo gbe jo.. Tori won Lolomo lo ...

Read More »
yoruba kids

Lakurubututu ! “Omo ya jo, omo le yeni”

Omolade,Omolowo,Omolola,Omo ni ola,Omoni’yi Omo’leye, Omolabake, Omolabage, Omopariola Omojowolo, Omosunbo, Omofowokade, Omofowokola Omotoriola, Omorinsola, Omorinsoye, Omobobola, Omoyosola Omoboboye, Omoyosade,Omoyosoye, Omodapomola, Omodapomoye Omoboriola, Omoboriola,Omotanshe,Omotanoshi, omo ju oun gbogbo lo, Aakun dabo ore wa toju omo re nitori awon ni Ojo ola re, gbogbo Eni ti o ti bi ko ni yan ku Agan ti ko ti bi,yio fi owo Osun pa omo lara, a ti se odun ajodun awon ewe ti odun yii, K’edumare je ki a tun se opolopo re lori ...

Read More »

Latest World News

Powered by themekiller.com anime4online.com animextoon.com apk4phone.com tengag.com moviekillers.com